Ẹkisodu 17:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Mose bá gbé ọwọ́ rẹ̀ sókè, àwọn ọmọ Israẹli a máa borí àwọn ará Amaleki, nígbà tí ó bá sì rẹ ọwọ́ sílẹ̀, àwọn ará Amaleki a máa borí àwọn ọmọ Israẹli.

Ẹkisodu 17

Ẹkisodu 17:6-13