Ẹkisodu 16:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó di ọjọ́ kẹfa, wọ́n kó ìlọ́po meji, olukuluku kó ìwọ̀n Omeri meji meji. Nígbà tí àwọn àgbààgbà Israẹli lọ sọ fún Mose,

Ẹkisodu 16

Ẹkisodu 16:15-27