Ẹkisodu 16:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ìrì náà kásẹ̀ nílẹ̀, wọ́n rí i tí kinní funfun kan tí ó dàbí ìrì dídì bo ilẹ̀ ní gbogbo aṣálẹ̀ náà.

Ẹkisodu 16

Ẹkisodu 16:4-15