Ẹkisodu 16:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí Aaroni ti ń bá gbogbo ìjọ eniyan Israẹli sọ̀rọ̀, wọ́n wo apá aṣálẹ̀, wọ́n sì rí i pé ògo OLUWA hàn ninu ìkùukùu.

Ẹkisodu 16

Ẹkisodu 16:9-12