Ẹkisodu 14:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ ni OLUWA ṣe gba Israẹli lọ́wọ́ àwọn ará Ijipti ní ọjọ́ náà, àwọn ọmọ Israẹli sì rí i bí àwọn ará Ijipti ti kú sí etí bèbè òkun.

Ẹkisodu 14

Ẹkisodu 14:24-31