Ẹkisodu 14:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó di òwúrọ̀ kutukutu, OLUWA bojú wo ogun Ijipti láti òkè wá, ninu ọ̀wọ̀n iná, ati ọ̀wọ̀n ìkùukùu, ó sì dẹ́rùbà wọ́n.

Ẹkisodu 14

Ẹkisodu 14:16-29