Ẹkisodu 14:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Angẹli Ọlọrun tí ó ti wà níwájú àwọn eniyan Israẹli bá bọ́ sẹ́yìn wọn, ọ̀wọ̀n ìkùukùu tí ó wà níwájú wọn náà bá pada sí ẹ̀yìn wọn.

Ẹkisodu 14

Ẹkisodu 14:11-24