Ẹkisodu 12:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n óo so ẹran wọn mọ́lẹ̀ títí di ọjọ́ kẹrinla oṣù yìí. Nígbà tí ó bá di ìrọ̀lẹ́ ọjọ́ náà, gbogbo ìjọ eniyan Israẹli yóo pa ẹran wọn.

Ẹkisodu 12

Ẹkisodu 12:1-16