Ẹkisodu 12:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn eniyan náà bá mú àkàrà tí wọ́n ti pò, ṣugbọn tí wọn kò tíì fi ìwúkàrà sí, wọ́n sì fi aṣọ so ọpọ́n ìpòkàrà wọn, wọ́n gbé e kọ́ èjìká.

Ẹkisodu 12

Ẹkisodu 12:29-39