Ẹkisodu 12:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Mose bá pe gbogbo àwọn àgbààgbà Israẹli jọ, ó sọ fún wọn pé, “Ẹ ṣa ọ̀dọ́ aguntan kọ̀ọ̀kan ní ìdílé yín kọ̀ọ̀kan, kí ẹ sì pa á fún ìrékọjá.

Ẹkisodu 12

Ẹkisodu 12:16-30