Ẹkisodu 12:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Láti ìrọ̀lẹ́ ọjọ́ kẹrinla oṣù kinni yìí títí di ìrọ̀lẹ́ ọjọ́ kọkanlelogun oṣù náà, burẹdi tí kò ní ìwúkàrà ni ẹ gbọdọ̀ máa jẹ.

Ẹkisodu 12

Ẹkisodu 12:15-20