Ẹkisodu 10:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bá mú Mose ati Aaroni pada tọ Farao lọ. Farao ní kí wọ́n lọ sin OLUWA Ọlọrun wọn, ṣugbọn ó bèèrè pé àwọn wo gan-an ni yóo lọ?

Ẹkisodu 10

Ẹkisodu 10:4-14