Ẹkisodu 10:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Farao bá tún ranṣẹ lọ pe Mose, ó ní, “Ẹ lọ sin Ọlọrun yín, ẹ máa kó àwọn ọmọ yín lọ pẹlu, ṣugbọn ẹ fi agbo aguntan yín ati agbo ẹran yín sílẹ̀.”

Ẹkisodu 10

Ẹkisodu 10:16-26