Ẹkisodu 1:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba yìí sọ fún àwọn eniyan rẹ̀ pé, “Ẹ wò bí àwọn ọmọ Israẹli wọnyi ti pọ̀ tó, tí wọ́n sì lágbára jù wá lọ.

Ẹkisodu 1

Ẹkisodu 1:3-12