Ẹkisodu 1:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, Ọlọrun ṣe àwọn agbẹ̀bí náà dáradára; àwọn eniyan Israẹli ń pọ̀ sí i, wọ́n sì ń lágbára sí i.

Ẹkisodu 1

Ẹkisodu 1:18-22