Ẹkisodu 1:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó yá, ọba Ijipti pe àwọn obinrin Heberu tí wọ́n ń gbẹ̀bí, tí orúkọ wọn ń jẹ́ Ṣifira ati Pua, ó sọ fún wọn pé,

Ẹkisodu 1

Ẹkisodu 1:6-19