Efesu 6:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin òbí, ẹ má ṣe mú àwọn ọmọ yín bínú. Títọ́ ni kí ẹ máa tọ́ wọn ninu ẹ̀kọ́ ati ìlànà ti onigbagbọ.

Efesu 6

Efesu 6:3-7