Efesu 5:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ẹ ṣọ́ra bí ẹ ti ń hùwà. Ẹ má ṣe hùwà bí ẹni tí kò gbọ́n, ṣugbọn ẹ hùwà bí ọlọ́gbọ́n.

Efesu 5

Efesu 5:12-18