Efesu 4:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí èyí ni Ìwé Mímọ́ ṣe sọ pé,“Nígbà tí ó lọ sí òkè ọ̀run,ó kó àwọn ìgbèkùn lẹ́yìn,ó sì fi ẹ̀bùn fún àwọn eniyan.”

Efesu 4

Efesu 4:4-15