Efesu 4:19-21 BIBELI MIMỌ (BM)

19. Wọn kò bìkítà: wọ́n ti fi ara wọn fún ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ara nípa oríṣìíríṣìí ìwà burúkú nítorí ojúkòkòrò.

20. Ṣugbọn a kò kọ́ ẹ̀yin bẹ́ẹ̀ nípa Kristi.

21. Ẹ ti gbọ́ nípa Jesu, a sì ti fi òtítọ́ rẹ̀ kọ yín,

Efesu 4