Efesu 1:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó fi agbára yìí hàn ninu Kristi nígbà tí ó jí i dìde ninu òkú, tí ó mú un jókòó ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀ lọ́run.

Efesu 1

Efesu 1:15-23