Efesu 1:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀mí Mímọ́ yìí jẹ́ onídùúró ogún tí a óo gbà nígbà tí Ọlọrun bá dá àwọn eniyan rẹ̀ nídè, kí á lè yin Ọlọrun lógo.

Efesu 1

Efesu 1:4-21