Diutaronomi 9:15 BIBELI MIMỌ (BM)

“Mo bá gbéra, mo sọ̀kalẹ̀ láti orí òkè pẹlu àwọn tabili òkúta mejeeji tí a kọ majẹmu náà sí ní ọwọ́ mi. Iná sì ń jó lórí òkè náà.

Diutaronomi 9

Diutaronomi 9:6-17