Diutaronomi 8:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Gẹ́gẹ́ bí àwọn orílẹ̀-èdè tí OLUWA parun fun yín, bẹ́ẹ̀ ni ẹ̀yin náà yóo parun, nítorí pé ẹ kọ̀, ẹ kò gbọ́ ti OLUWA Ọlọrun yín.

Diutaronomi 8

Diutaronomi 8:11-20