Diutaronomi 8:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ ranti OLUWA Ọlọrun yín nítorí òun ni ó fun yín ní agbára láti di ọlọ́rọ̀, kí ó lè fìdí majẹmu tí ó fi ìbúra bá àwọn baba yín dá múlẹ̀, bí ó ti rí lónìí.

Diutaronomi 8

Diutaronomi 8:14-20