Diutaronomi 8:16 BIBELI MIMỌ (BM)

ẹni tí ó fi mana tí àwọn baba yín kò jẹ rí bọ́ yín ninu aṣálẹ̀, kí ó lè tẹ orí yín ba, kí ó sì dán yín wò láti ṣe yín ní rere níkẹyìn.

Diutaronomi 8

Diutaronomi 8:6-20