Diutaronomi 7:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ kò gbọdọ̀ fi ọmọ yín fún àwọn ọmọkunrin wọn láti fẹ́, bẹ́ẹ̀ ni ẹ kò gbọdọ̀ fẹ́ ọmọ wọn fún àwọn ọmọkunrin yín.

Diutaronomi 7

Diutaronomi 7:1-11