Diutaronomi 7:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn OLUWA Ọlọrun yín yóo fi wọ́n lé yín lọ́wọ́, yóo sì mú kí ìdàrúdàpọ̀ bẹ́ sílẹ̀ ní ààrin wọn títí tí wọn yóo fi parun.

Diutaronomi 7

Diutaronomi 7:19-26