Diutaronomi 7:18 BIBELI MIMỌ (BM)

ẹ ranti ohun tí OLUWA Ọlọrun yín ṣe sí Farao ati gbogbo ilẹ̀ Ijipti. Nítorí náà, ẹ kò gbọdọ̀ bẹ̀rù wọn.

Diutaronomi 7

Diutaronomi 7:8-22