Diutaronomi 6:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ gbọdọ̀ pa àwọn òfin OLUWA Ọlọrun yín mọ́ dáradára, kí ẹ sì máa tẹ̀lé àwọn òfin ati àwọn ìlànà rẹ̀, tí ó fi lélẹ̀ fun yín.

Diutaronomi 6

Diutaronomi 6:8-25