Diutaronomi 6:12 BIBELI MIMỌ (BM)

ẹ ṣọ́ra kí ẹ má baà gbàgbé OLUWA tí ó mú yín jáde láti ilẹ̀ Ijipti, níbi tí ẹ ti jẹ́ ẹrú.

Diutaronomi 6

Diutaronomi 6:10-16