Diutaronomi 5:32 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nítorí náà, ẹ ṣọ́ra kí ẹ sì ṣe gbogbo ohun tí OLUWA Ọlọrun yín pa láṣẹ fun yín; ẹ kò gbọdọ̀ ṣe àìgbọràn ninu ohunkohun.

Diutaronomi 5

Diutaronomi 5:29-33