Diutaronomi 5:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Kì í ṣe àwọn baba wa ni OLUWA bá dá majẹmu yìí, ṣugbọn àwa gan-an tí a wà láàyè níhìn-ín lónìí ni ó bá dá majẹmu náà.

Diutaronomi 5

Diutaronomi 5:2-11