Diutaronomi 5:23 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nígbà tí ẹ gbọ́ ohùn láti inú òkùnkùn biribiri, tí iná sì ń jó lórí òkè, gbogbo àwọn olórí ẹ̀yà yín ati àwọn àgbààgbà wá sọ́dọ̀ mi;

Diutaronomi 5

Diutaronomi 5:21-24