Diutaronomi 5:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn èmi a máa fi ìfẹ́ mi, tí kì í yẹ̀, hàn sí ẹgbẹẹgbẹrun àwọn tí wọ́n fẹ́ràn mi, tí wọ́n sì ń tẹ̀lé òfin mi.

Diutaronomi 5

Diutaronomi 5:1-14