Diutaronomi 4:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Tabi orílẹ̀-èdè ńlá wo ni ó tún wà, tí ó ní ìlànà ati òfin òdodo gẹ́gẹ́ bí àwọn tí mo gbé ka iwájú yín lónìí?

Diutaronomi 4

Diutaronomi 4:1-14