Diutaronomi 4:39 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí ẹ mọ̀ lónìí, kí ó sì da yín lójú pé, OLUWA ni Ọlọrun; kò sí ọlọrun mìíràn mọ́ ní ọ̀run ati ní ayé.

Diutaronomi 4

Diutaronomi 4:31-48