Diutaronomi 4:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Níbẹ̀ ni ẹ óo ti wá OLUWA Ọlọrun yín tí ẹ óo sì rí i, tí ẹ bá wá a tọkàntọkàn pẹlu gbogbo ẹ̀mí yín.

Diutaronomi 4

Diutaronomi 4:28-34