Diutaronomi 4:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun ba yín sọ̀rọ̀ láti inú iná náà wá, ẹ gbọ́ ohùn rẹ̀, ṣugbọn ẹ kò rí i. Ohùn rẹ̀ nìkan ni ẹ̀ ń gbọ́.

Diutaronomi 4

Diutaronomi 4:7-17