Diutaronomi 34:3 BIBELI MIMỌ (BM)

ilẹ̀ Nẹgẹbu ni apá gúsù ati gbogbo pẹ̀tẹ́lẹ̀ tí ó wà ní àfonífojì Jẹriko, ìlú tí ó kún fún ọ̀pẹ, títí dé ilẹ̀ Soari.

Diutaronomi 34

Diutaronomi 34:2-12