Diutaronomi 34:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Kò sì sí ẹlòmíràn tí OLUWA rán láti ṣe ọpọlọpọ iṣẹ́ ìyanu lára Farao ati gbogbo àwọn iranṣẹ rẹ̀ ati gbogbo ilẹ̀ rẹ̀, ní ilẹ̀ Ijipti.

Diutaronomi 34

Diutaronomi 34:6-12