Diutaronomi 33:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ ni OLUWA ṣe di ọba ní Jeṣuruni,nígbà tí gbogbo àwọn olórí péjọ,àní, gbogbo àwọn olórí ninu ẹ̀yà Israẹli.

Diutaronomi 33

Diutaronomi 33:1-10