Diutaronomi 33:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó súre fún Sebuluni ati fún Isakari, ó ní:“Máa yọ̀ bí o ti ń jáde lọ, ìwọ Sebuluni,sì máa yọ̀ ninu ilé rẹ, ìwọ Isakari.

Diutaronomi 33

Diutaronomi 33:11-28