Diutaronomi 33:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí àwọn òkè ńláńlá àtijọ́ so ọpọlọpọ èso dáradára,kí ọpọlọpọ èso sì bo àwọn òkè kéékèèké.

Diutaronomi 33

Diutaronomi 33:10-25