Diutaronomi 32:52 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, o óo fi ojú rí ilẹ̀ náà, ṣugbọn ẹsẹ̀ rẹ kò ní tẹ ilẹ̀ tí n ó fún àwọn eniyan Israẹli.”

Diutaronomi 32

Diutaronomi 32:49-52