Diutaronomi 32:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí iná ibinu mi ń jó,yóo sì jó títí dé isà òkú.Yóo jó ayé ati ohun gbogbo tí ń bẹ ninu rẹ̀ ní àjórun,tó fi mọ́ ìpìlẹ̀ àwọn òkè ńlá.

Diutaronomi 32

Diutaronomi 32:12-23