Diutaronomi 31:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Mose bá kọ òfin yìí sílẹ̀, ó fún àwọn alufaa, àwọn ọmọ Lefi tí wọ́n ru àpótí majẹmu OLUWA ati gbogbo àwọn àgbààgbà Israẹli.

Diutaronomi 31

Diutaronomi 31:6-15