Diutaronomi 31:26 BIBELI MIMỌ (BM)

ó ní, “Ẹ fi ìwé òfin yìí sí ẹ̀gbẹ́ àpótí majẹmu OLUWA Ọlọrun yín, kí ó wà níbẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ẹ̀rí pẹlu yín;

Diutaronomi 31

Diutaronomi 31:20-30