Diutaronomi 31:19 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nítorí náà, kọ orin yìí sílẹ̀ nisinsinyii kí o sì kọ́ àwọn ọmọ Israẹli, kí orin náà lè jẹ́ ẹlẹ́rìí mi lọ́dọ̀ wọn.

Diutaronomi 31

Diutaronomi 31:18-24