Diutaronomi 31:15 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA fi ara hàn wọ́n ninu ọ̀wọ̀n ìkùukùu ninu àgọ́ náà. Ọ̀wọ̀n ìkùukùu náà wà ní ẹ̀bá ẹnu ọ̀nà àgọ́.

Diutaronomi 31

Diutaronomi 31:8-18